Bísọ́ọ̀bù Àgbà Orílẹ̀-èdè South Africa Tọrọ Àforíjì Látàrí Ẹ̀sùn Ìlòkulò Ọmọdé
Bísọ́ọ̀bù àgbà ti ìlú Cape Town se ìpàdé ní ọjọ́ ìṣẹ́gun lẹ́yìn àgbéyẹ̀wò tí wọ́n rí pé àwọn ìgbìmọ̀ mọ̀ pé ìjọ Anglican ni South Africa kùnà láti sọ fún àwọn ìjọ míràn ewu tó lágbára tó wà níbẹ látàrí ìlòkulò ọmọdé lọ́wọ́…