Take a fresh look at your lifestyle.

Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Gbá Látí Só Ìbáṣepọ̀ Wọ́n Pẹ̀lú Iran Lé dọin-dọin

Ààrẹ Muhammadu Buhari tí fí dá Ìgbákejì Ààrẹ orílẹ̀-èdè Iran lójú pé òún ṣetán láti sọ d'ọtun ìbáṣepọ̀ tó wà lọwọ́ pẹ̀lú Orílẹ̀-èdè Iran Ààrẹ Buhari sọ èyí lásìkò tí Ìgbákejì Ààrẹ orílẹ̀-èdè Iran, Mohsen Mansouri ṣé àbẹwò sí níbí ìpàdé…

Nàìjíríà Àtí Íńdíà Ṣe Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Lórí Ìwádìí Ìmọ-jinlẹ̀ Ojú-ọjọ́ Àtí Ìdàgbàsókè

Ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti ìjọba orílẹ̀-èdè India tí fọwọ́ sí ìwé àdéhùn (MoU) fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ lórí iṣẹ́ ìmọ-jinlẹ̀ ojú-ọjọ́, ìwádìí ìmọ-ẹrọ àtí ìdàgbàsókè. Àdéhùn náà ní a fọwọ́ sí ní orúkọ Ilé-iṣẹ́ Oju-ọjọ Nàìjíríà (NiMet)…

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Rivers Ṣé Ìfilọ́lẹ̀ Pápákọ̀ Òfurufú Ní Olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́

Gómìnà Nyesom Wike ti ìpínlẹ̀ Rivers tí ṣé ìfilọ́lẹ̀ ìṣẹ́ àkànṣe mẹ́ta bíí, ilé èpò ọkọ̀ òfurufú, ọ̀nà àbáwọlé pápá ọkọ̀ òfurufú àti ọgbà ìtura, gbogbo rẹ̀ ní pápákọ̀ òfurufú Ìbàdàn, olú ìlú ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Wike ṣé ìfilọ́lẹ̀ ilé ọkọ̀…

Ìgbákejì Ààrẹ Kí Bola Tinubu Kú Oríìré Fún Ìdìbò Yàn Gẹ́gẹ́ Bí Ààrẹ Túntún

Ìgbákejì Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Ọ̀jọ̀gbọ́n Yemi Osinbajo tí kì Ààrẹ túntún tí á dìbo yàn nínú ìdìbò Ààrẹ 2023, Bola Ahmed Tinubu. Olùrànlọwọ pàtàkì ìgbákejì Ààrẹ náà lórí ètò Ìròyìn àtí Ìpolongo, Laolu Akande sọ èyí dì mímọ̀ ní…
button