Mínísítà fún ìdàgbàsókè àwọn ọdọ àtí èrè ìdárayá, Sunday Dare tí kì Olúbóri nínú Ìdìbò Ààrẹ tí ọdún yìí, olùdíje fún ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress, APC, Asiwaju Bola Ahmed Tinubu.
Ìkíni rẹ̀ tó wà nínú Gbólóhùn tí a samisi pé “Tinubu Ọlọgbọn àtí Alaanu Asíwájú” (Tinubu Cerebral and Compassionary Leader) ṣé àpèjúwe Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó tẹ́lẹ̀ rí gẹ́gẹ́ bí Ọkùnrin tó ní ìtara púpọ fún Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti ifẹ̀ látí ní ipá lórí Ìgbésí ayé àwọn tálákà sí réré.
Ó fí kún pé ìṣẹgun rẹ̀ ní ilé ìbò jẹrìí sí àwọn ibasepọ rẹ̀ pẹ̀lú àwọn aráàlú fún bí iwọn ọdún mẹ́wàá sẹyìn.
Tún kà nípa:Ẹgbẹ́ Agbábọ́ọ̀lù Kwara United Yan Kabir Dogo Gẹ́gẹ́ Bí Akọ́ni-mọ̀ọ́gbá
Ó tèsíwájú pé ìgbésí Aye Gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó tẹ́lẹ̀ kún fún ẹrí àwọn ìṣòro àti ìpenija tí a rò pé kò ní níyànjú ṣùgbọ́n tó yanjú rẹ̀ báyìí.
O fí ìgboyà hàn pé yóò gúnlè àṣeyọrí réré tí Ààrẹ Muhammadu Buhari yóò sì mú Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lọ́ síbí gíga.
“Kí Orílẹ̀-èdè gbá ìtèsíwájú àtí ìtura lábẹ́ ìjọba rẹ̀.”
[…] Tún kà nípa: Mínísítà Ìdárayá Kí Ààrẹ Túntún Tí Á Fibò Yàn Kú Oríìré […]