Ìṣòro Wà Látí Ṣé Àwárí Duroonu Tó Já Sí Òkun Dúdú – Ìjọba America
Ọkọ ìjà òfurufú America kàn tí wọ́n fí ń wó àyíká Orílẹ̀-èdè Ukraine já lulẹ̀ lẹyìn tí ọkọ ìjà Òfurufú Russia ṣé ìkọlù sí. Èyí ló ṣòro látí wá lẹyìn tó jábo sínú ọ̀gbùn Okùn Dúdú, ọkàn nínú àwọn ọgá àgbà ọmọ ogún Orílẹ̀-èdè America sọ́,…