Take a fresh look at your lifestyle.

Mozambique Bẹ̀rẹ̀ Àtúnṣe Àgbègbè Kàn Lẹyìn Ìjì Líle Cyclone

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 230

Ààrẹ Mozambique, Filipe Nyusi tí kéde ìpínu rẹ̀ látí pín mílíọ̀nù mẹ́ta lé díẹ̀ fún àtúnkọ àwọn ilé-ìwé, ilé ìgbé àtí àwọn òun amàyédẹ́rùn mìíràn bótílẹ̀jẹ́pé owó náà kere púpọ̀.

Ìjì líle náà ṣẹ̀lẹ̀ ní òpin ọ̀sẹ̀ tó kọjá, ẹ́lẹ̀ẹ́kéji irú rẹ̀ nínú oṣù kàn.

Ìròyìn sọ pé Ojo àrọ́ọ̀rọ̀da tó rọ̀ ní orílẹ̀-èdè Mozambique láàrín ọ̀sẹ̀ mẹ́rin jú èyí tó ń rọ̀ láàrín ọdún kàn lọ́. Ó kéré jù, ènìyàn mẹ́ta lé làádọ́ta ló tí pàdánù ẹ̀mí wọ́n tí ọgọ́ọgọrún ẹgbẹ̀rún àwọn mìíràn wà nínú èwù àtí ìdààmú.

Tún kà nípa: Àwọn Ẹ̀ṣọ́ Aláàbò Ń Gbìyànjú Láti Dóòlà Ẹ̀mí Lẹ́yìn Ìsẹ̀lẹ̀ Omíyalé Ní Orílẹ̀ Èdè Mozambique

Ààrẹ Nyusi náà ṣàbẹwò sí àwọn àgbègbè tí ìṣẹ̀lẹ̀ náà tí ṣẹ̀ ní Ọjọ́rú ní àárín Ilú Zambezia

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button