Ètò Ẹ̀yawó Àwọn Ọmọ Ilé-ìwé Tí 2024/2025 Yóò Bẹ̀rẹ̀ Ní Oṣù Kejì, Ọdún Yìí
Ètò ẹ̀yawó àwọn akẹ́kọ̀ọ́ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà 'Nigeria Education Loan Fund NELFUND', ní wọ́n yóò faye gbá ìforúkọsílẹ̀ fún tí ọdún 2024/2025 yóò bẹ̀rẹ̀ ọjọ́ kejìlélogún, Oṣù Kejì, Ọdún 2025.
Wọ́n tún sọ pé tí ọdún 2023/2024 ní yóó wá…