Take a fresh look at your lifestyle.

Manchester United Pàdánù Ìfẹsẹ́wọ́sẹ̀ Wọ́n Pẹ̀lú Tottenham 1-0

Lekan Orenuga

141

James Maddison gbá ayo àkọkọ́ wọlé fún ìkọ Tottenham lẹ́yìn ifarapa rẹ̀ nínú ìdíje English Premier League bí wọ́n ṣé bóri ìkọ Manchester United pẹ̀lú ayo kán sí odò (1-0) ní ìlú London, England.

‎ Èyí ní ìgbà àkọkọ́ tí Tottenham yóò bóri ifẹsẹwọsẹ wọ́n lẹ́yìn ifẹsẹwọsẹ márùndínláàdọ́fà lábẹ́ oluṣakoso wọ́n ọmọ Orílẹ̀-èdè Australia, Ange Postecoglou bí wọ́n ṣé bọ́ sókè Manchester United lórí tábìlì English Premier League sí ipò Kejìlá.


‎ Alàkóso Manchester United, Ruben Amorim, náà ló tí pàdánù ifẹsẹwọsẹ mẹjọ nínú ifẹsẹwọsẹ mẹrinla láti ìgbà tó tí gbá iṣẹ́ nínú ìkọ náà.

Comments are closed.

button