Àwọn Ẹgbẹ́ Kàn Bú Ẹnu àtẹ Lù Bí Ìjọba Ìpínlè Nassarawa Ṣé Kọ̀ ìhà Aibikita Sí Ifeto-sọmọ-bibi
Àìní iṣeto owo Ìjọba Ìpínlè Nassarawa lo fa idiwọ lati kojú Ifeto-somo-bibi ni ipinlẹ naa.
Eyi ni Àjọ Pathfinder International tọka sí níbí ètò ti wọn ṣe pẹlú ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ẹgbẹ Asopọ Agbegbe fun Ilera ati Ikede Abẹ́lé Fun…