Làsígbòò Palma:Àwọn aládúgbò sá àsálà fún ẹ̀mí wọn
Àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Mozambic ti agbègbè Palma ti wà ní hílàlílo, tí ọgọ́rùún sí ńsá lọ lójoojúmọ́, bótilẹ̀jẹ́ pé ,ó tí tó ọ̀sẹ̀ mẹ́fà sẹ́yìn tí àwọn mùsùlùmí oníjà kan kọlù ìlú náà, gẹ́gẹ́ bíi…