Ààrẹ oríle-èdè Sòmálíà kọ̀ jálẹ̀ lórí lílé Aṣojú
Ààrẹ orílẹ̀-èdè Somalia Mohamed Abdullahi Farmaajo ti kọ ìgbésẹ̀ Mínísítà láti lé asojú pàtàkì fún Ẹgbẹ́ Adúláwọ̀ kúrò ní orílẹ̀-èdè náà.
Minisita Mohamed Hussein Roble sọ tẹlẹ pe ohun ko fẹ ri mọ fun kikopa…