Take a fresh look at your lifestyle.

Mínísítà Gbàdúrà Fún Àwọn olùfaragbà Ìkọlù ọkọ̀ ojú irin Kàdúná

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 201

Ìgbìmọ̀ Aláse àpapọ̀  ṣe ìpalọ́lọ́ ìṣẹ́jú kan  fún àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n pàdánù ẹ̀mí wọn níbi ìkọlù ọkọ̀ ojú irin tí ó ṣẹlẹ̀ ní ọjọ́ ajé ní Ìpínlẹ̀ Kàdúná.

Akowe si ijoba ti apapọ, Boss Mustapha ran igbimo leti nipa isẹlẹ aburu ti o ṣelẹ laipẹ diẹ ṣaaju ibẹrẹ ipade naa.

Nibayi, Aare Muhammadu Buhari n dari ipade   Igbimọ Alase apapọ lori ayelujara, ti o waye ni awọn i Ile-igbimọ orile-ede,ni ilu Abuja.

Igbakeji Aarẹ Yẹmi Ọsinbajo, Akọwe  ijoba apapọ, Boss Mustapha ati Oloye Oṣiṣẹ si Aarẹ ati Ọjọgbọn Ibrahim Gambari wa nijoko naaa, eyiti o bẹrẹ ni agogo mẹsan owurọ.

Lara awon ti o tun wa nibẹ ni ọga agba fun awọn oṣiṣẹ ijọba apapọ, Dokita Fọlashade Yẹmi-Ẹsan, awọn minisita fun eto iroyin ati asa, Lai Mohammed, eto inawo, eto isuna ati eto orileede, Zainab Ahmed, idajo, Abubakar Malami, ati ti ise ati ile, Babatunde. Fashola.

Alaye nigbamiran…

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button