Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn Òṣìṣẹ́ Gírííkì rawọ́lé ìyanṣẹ́lódì Lórí Owó iṣẹ́ tí kò tí ǹkan

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 239

Àwọn òṣìṣẹ́ Gírííkì bẹ̀rẹ̀ ìdaṣẹ́sílè ọlọ́jọ́ jákèjádò orílẹ̀-èdè ní ọjọ́ọ́rú,lórí ááwọ̀ bí gbogbo nǹkan ṣe gbówólórí àti owó-iṣẹ́ tí kò tó ǹkan, ìdálọ́wọ́dúró gbígbé, àwọn ọkọ̀ ojú-omi kékéèké, àwọn ilé-ìwé àti àwọn ilé-ìwòsàn gbogboogbò.

Awọn ẹgbẹ oṣiṣẹ meji to tobiju lorilẹ-ede, awọn oṣiṣe ijọba ati oṣiṣẹ aladani to to milionu meji aabọ ,ni o pe fun idaṣẹsilẹ gbogbogbo ti yoo pari pẹlu ifẹhonuhan ni aarin Athens.

Ẹgbẹ aladani lorilẹ-ede, GSEE sọ pe, “Fun ọdun mẹrinla sẹhin,ni idaamu ti deba awọn oṣiṣẹ lori owo-wiwọle ati igbesi aye wọn.

“Bi  ọdun ṣ n gori ọdun ni idaamu yii n pọ si,aawọ n jinlẹ nigbagbogbo,ti awọn ẹtọ wa naa n dinku.”

Greece bọ ninu  idaamu owo lẹyin ọdun mẹwa ni ọdun 2018, ajakaye-arun COVID-19 tun mu irin-ajo agbaye wa si iduro ni ọdun meji lẹhinna, ni eyi ti o mu ipalara ba ile-iṣẹ irin-ajo pataki rẹ.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button