Take a fresh look at your lifestyle.

Hajj Ọdun 2022: FCTA Ṣètò afikún owó àsansílẹ̀ fún Àwọn Arìnrìn àjò mímọ́ Hajj

Àjọ àwọn mùsùlùmí ti ìṣàkóso ìjọba àpapọ̀ olú ìlú Nàìjíríà, FCTA, ti fún àwon arìnrìn àjò mímọ́  láti se Hajj odun yìí ní orílẹ̀-èdè Saudi Arabia títí di ọjọ́ kẹtàlá oṣù karùn-ún láti fi kún owó…

Títò fépo:Epo pẹtiróólù rírà di bóòlọ o yà ńmi ní ìlú Àbújá

Ilé-iṣẹ́ tó ń mójútó ọ̀rọ̀ epo ilẹ̀ ní orílè-èdè Nàìjíríà, NNPC, sọ pé ó ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn alábàátajàpọ̀  rẹ̀ láti ṣàlékún gbígbé epo mọ́tò, (PMS) tí a tún mọ̀ sí pẹtirólù ní gbogbo àwọn ilé-ìpamọ́…

Nàìjíríà yóò Darí Ìpàdé Àgb́aýe Lórí Àpèjọ ẹ̀kọ́ Àwùjọ ọdún 2022

Ẹgbẹ́ ètò ìbáraẹnisọ̀rọ̀ laarin awọn orilẹ-ede, (ITU) ti yan Mínísítà fún Ìbáraẹnisọ̀rọ̀ àti ọrọ̀-Ajé lórí ayélujára, Ọ̀jọ̀gbọ́n Isa Pantami, gẹ́gẹ́ bí Alága Àgbáyé lórí ọ̀rọ̀ Àwùjọ  (WSIS),ọdún 2022. Ipade naa…

Mozambique ń gbìmọ̀ ètò Òfin Láti Ṣàtúnṣe Àti láti gba owó-orí àwọn ilé ìjọsìn

Mozambique ń gbìmọ̀ òfin tuntun kan tí yóò máa ṣàkóso ìgbòkègbodò àwọn ṣọ́ọ̀ṣì, tí wọn yóò fi le gbowó orí wọn, tí yóò sì  pé kí wọ́n ní iye tí ó kéré jù igba ìfọwọ́sí láti lè forúkọ sílẹ̀. Minisita Idajọ, T’olofin ati Ọran  Ẹsin,…

Àáyà bẹ́ sílẹ̀ ó bẹ́ séré, a ti setan fún dídásílẹ̀ Ilé-ẹ̀kọ́ gíga àpapọ̀ ti ìlera…

Gómìnà ìpínlẹ̀ Òṣun, Adégbóyèga Oyètọ́lá sọ pé ìpínlẹ̀ náà ti ṣetán fún  Ilé-ẹ̀kọ́ gíga àpapọ̀ ti ìlera àti ìmọ̀ sáyéńsì, Ìlá-Ọ̀ràngún tí wọ́n fọwọ́sí láìpẹ́ yìí ní ìjọba ìbílẹ̀ Ìlá ní ìpínlẹ̀…
button