Take a fresh look at your lifestyle.

Orílẹ̀-èdè Philippine Bẹ̀rẹ̀ Ìdìbò Yan Ààrẹ tuntun

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 36

Orílẹ̀-èdè Philippine bẹ̀rẹ̀ ìdìbò láti yan Ààrẹ tutun  ní ọjọ́ ajé àti ẹgbàásán

òṣìṣẹ́ mìíràn láti gbogbo àwọn ìpele  ìjọba.

Awọn oludije ti wọn yoo yan ni igbakeji aarẹ,awọn aṣofin mejila, awọn ọmọ ẹgbẹ  Ile-igbimọ Aṣoju ti o ju ọọdunrun lọ ati awọn oṣiṣẹ ijọba agbegbe ti o ju ẹgbàájọ lọ.

Ijọba ti fi awọn ọmọ ogun ẹ̀ẹ́dẹ́gbàta ĺe ńi ọ̀kẹ́ mèjì ati awọn osiṣẹ

ọlọpa ọ̀kẹ́ mẹ̀ta ṣe alabojuto eto alaafia lakoko awọn idibo.

Afikun ọlọpa ẹgbàáfà wa ni imurasilẹ ti iwa-ipa nle  ba waye ni awọn agbegbe kan.

Leave A Reply

Your email address will not be published.