Take a fresh look at your lifestyle.

Covid-19:Àwọn ènìyàn mẹ́ẹ̀dógún- dín- lọ́́rìn- lé-lọ́ọ̀dúnrún míràn tún ti ní ààrùn…

Ilé-iṣẹ́ tó ń ṣàkóso àjàkalẹ̀ ààrùn NCDC ti kéde pé ènìyàn mẹ́ẹ̀dógún-dín –lọ́rìn-lé-lọ́ọ̀dúnrún míràn àn tún ti ní ààrùn covid tí méjọ sì jẹ́pè ọlọ́run ní ọjọ́ kejìlá oṣù kẹsàn-án,ọdún 2021.…

Ẹgbẹ́ ọmọ ogun Bẹ́rẹ̀ẹ̀ ìpele Kejì, ìkẹta Àpèjọ COAS Lónìí

Ọ̀gá àgbà  fún àwọn ọmọ -ogun ti bẹ̀rẹ̀ àpapọ̀ Àpèjọ ìpele Kejì àti Kẹta tí ọdún  2021, ní Ìlú Àbújá ní ọjọ́ kẹtàlá,ọjọ́ àìkú, Oṣù Kẹsàn- án,ọdún 2021. Apejọ COAS yii n waye ni ibujoko Ile – igbalejo ti o wa…

A mú ètò ààbò lọ́kúnkúndùn ju ètò ọrọ̀ ajé lọ- Mínísítà ètò ìbáraẹnisọ̀rọ̀

Mínísítà fún ètò Ìbáraẹnisọ̀rọ̀ àti ọ̀rọ̀ ajé orí ayélujára, Ọ̀jọ̀gbọ́n Isa Pantamí, sọ pé ẹ̀ka ìbáraẹnisọ̀rọ̀  mú  ààbò lọ́kúnkúndùn ju àwọn àǹfàní ètò -ọrọ̀ ajé lọ. O sọ eyi  ni ilu Abuja, lakoko ayẹyẹ…

Àwọn ìyàwó àwọn gómìnà Àriwá gbógun ti ìwà ìṣègbèfábo-akọ àti lílo òògùn…

Àpèjọ Àwọn ìyàwó gómìnà Àriwá, N-GWF sọ pé àfọkàn sùn òhun  fún ọdún 2021-2022, ni láti kojú ìṣègbèfábo-akọ àti lílo òògùn olóró ní agbègbè Áriwá. Ninu awọn asọye rẹ, Alaga  Apejọ Awọn iyawo  gomina…
button