Take a fresh look at your lifestyle.

Covid-19:Àwọn ènìyàn mẹ́ẹ̀dógún- dín- lọ́́rìn- lé-lọ́ọ̀dúnrún míràn tún ti ní ààrùn covid

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 283

Ilé-iṣẹ́ tó ń ṣàkóso àjàkalẹ̀ ààrùn NCDC ti kéde pé ènìyàn mẹ́ẹ̀dógún-dín –lọ́rìn-lé-lọ́ọ̀dúnrún míràn àn tún ti ní ààrùn covid tí méjọ sì jẹ́pè ọlọ́run ní ọjọ́ kejìlá oṣù kẹsàn-án,ọdún 2021.

Lọwọlọwọ bayii,eniyan ookan-din-nigba-ẹgbẹrun-le-ni-ookan –le-laadọjọ eniyan loti ni aarun ọhun,eniyan ẹgbàáta- le- ni- ọ̀kẹ́ mẹ̀sán- o- le- ni- èjì- din- ni- okòó-le-ni-irinwó ti gba iwosan, ti apapọ eniyan to ti jẹ ipe oluwa si jẹ èjì- din- ni- ẹgbẹ́ẹ̀talá ni ipinlẹ mẹrindin-logoji ati olu-ilu.

Awọn eniyan tuntun mẹẹdogun-din-lọọrin-le-lọọdunrun to ṣẹṣẹ ni aarun covid yii jẹyọ ni awọn ipinlẹ mẹjọ –

Lagos (mẹsan-an –le-nigba) ,Ọndo (mejidin-laadọrun) ,Olu-ilu (mọkanle-lọgbọn) , Rivers (mẹrindin-logun) ,Ebonyi (mọkanla), Kaduna (mẹfa), Ekiti (mẹta) ,Plateau (ẹyọkan).

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button