Àwọn Òṣìṣẹ́ Gírííkì rawọ́lé ìyanṣẹ́lódì Lórí Owó iṣẹ́ tí kò tí ǹkan
Àwọn òṣìṣẹ́ Gírííkì bẹ̀rẹ̀ ìdaṣẹ́sílè ọlọ́jọ́ jákèjádò orílẹ̀-èdè ní ọjọ́ọ́rú,lórí ááwọ̀ bí gbogbo nǹkan ṣe gbówólórí àti owó-iṣẹ́ tí kò tó ǹkan, ìdálọ́wọ́dúró gbígbé, àwọn ọkọ̀ ojú-omi…