Gómìnà Nwifuru Gbóríyìn Fún Àwọn Àṣeyọrí Ni Orísirísi Ọnà Ni Ìpínlẹ̀ Ebony.
Gómìnà Francis Nwifuru ti gbóríyìn fún àwọn àṣeyọrí àti àwọn ìdàgbàsókè to sẹlẹ̀ ni ìpínlẹ̀ Ebony nipa ètò Ẹ̀kọ́ àti ìlera.
Nwifuru so èyí di mímọ̀ lásìkò to n ṣe idupẹ nile ìjósìn láti sààmì sí ayẹyẹ ọdun ìjọba awaarawa ni Abakaliki.…