Take a fresh look at your lifestyle.

Anti-Gay Bill: Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ghana Tí Ń Jà Fítáfítá Láti Dènà Òfin Ìbálòpọ̀ Ọkùnrin Àtí Ọkùnrin

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 263

Ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin ní Orílẹ̀-èdè Ghana tí ṣé àtìlẹ́yìn àtúnṣe sí ìwé-àṣẹ làti wọ́n ìjìyà ẹwọn ọdún mẹ́ta fún ẹnikẹ́ni tó bá tún polongo pẹ̀lú ìdánimọ̀ Ìbálòpọ̀ Ọkùnrin àti Ọkùnrin, Obínrin àtí Obínrin bíi LGBT.

Àwọn ènìyàn tó bà tún ṣé ìpolongo fún àwọn ètò LGBT lórílẹ̀-èdè náà, tún lè dojukọ ọdún mẹ́wàá 10 nínú túbú.

Àwọn aláṣẹ yóò tún ṣé àyẹwò àbàdófin náà finnifinni kí wọ́n tó sọ dì òfin.

Irúfẹ́ ìbálòpọ̀ báyìí ní òfin Ilé Ghana tí lòdì sí tẹlẹ.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button