Take a fresh look at your lifestyle.

Ọwọ́ Òfin Tẹ̀ Òṣìṣẹ́ Ilé-iṣẹ́ Oúnjẹ Kàn Ní Kenya Látàrí Ìtẹ Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn Lójú Mọlé

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 378

Ọwọ́ àwọn ọlọ́pàá tí bá àwọn òṣìṣẹ́ ilé oúnjẹ Kenya mẹ́ta kàn lẹyìn ẹsùn ifipa bọ́ṣọ́ lọrùn àwọn òṣìṣẹ́ bìrin wọ́n láti ṣàyẹ̀wò ẹní tí ó ùn ṣé nkán oṣù rẹ̀ lọ́wọ́, ìròyìn abẹ́lé sọ.

Nínú àlàyé kàn lórí ojú òpó ayélujára Ilé-iṣẹ́ Oúnjẹ náà “Brown’s Food Company” sọ pé o jẹ́ òun “ìbànújẹ” àtí pé ọrọ náà “kó ṣé àfihàn ìlànà tí ilé-iṣẹ́ náà lápapọ̀.”

Ìṣẹlẹ náà wáyé ní ọjọ́ kẹ́rin, Oṣù Keje, èyí tí gbogbo ènìyàn ṣé àkíyèsí rẹ̀ lẹyìn tí Sẹnẹtọ Gloria Orwoba kojú ilé-iṣẹ́ náà lórí ifiweranṣẹ Facebook kàn, fún itiju àti ilokulo àwọn Obìnrin náà.

Gẹ́gẹ́ bí fanran náà, òṣìṣẹ́ àgbà kán ní Brown ní wọ́n sọ pé o ríi aṣọ igbẹjẹ nínú àpótí tí kó tọ.

Òṣìṣẹ́ náà wà fí ẹsùn kàn àwọn òṣìṣẹ́ Obìnrin tí ẹ̀kà náà láti fí ọrọwerọ ṣùgbọ́n kó sí ẹní tó jẹwọ sí ìṣẹlẹ̀ náà. Èyí ló fá ifipa bọ̀ṣọ̀ lọrùn àwọn òṣìṣẹ́ binrin náà látí mọ́ ẹní tí ń ṣé nkán oṣù rẹ̀. Bi Sẹnetọ náà ṣé sọ nínú ọrọ rẹ̀.

Brown sọ pé wọ́n tí dá ẹní náà dúró ní ilé-iṣẹ́ náà titi di ẹyìn ìwádìí.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button