Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Bola Ahmed Tinubu tí kọ̀wé sí Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣojú ṣòfìn látí ṣé àkíyèsí àwọn olórí ológun títún ní orílẹ̀-èdè yìí.
Agbẹnusọ ilé-ìgbìmọ̀ aṣojú ṣòfin Honourable Tajudeen Abbas ló ká ìwé náà ní ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin.
Ìwé náà ló ṣé àfihàn olórí ilé iṣẹ́ ààbò túntún ní orílẹ̀-èdè wà èyítí ó nílò àyẹwò àpapọ̀ tí Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin àtí Ilé-iṣẹ́ Ààrẹ.
Tún kà nípa:Ààrẹ Nàìjíríà Tí Fọwọ́sí Àwọn Ìwé-àṣẹ Àṣẹ Mẹ́rin Kàn
Ó sọ pé orúkọ àwọn Ológun náà ní wọ́n tí fí ránṣẹ́ sí Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin Àpapọ̀ fún àtúnyẹwò àtí ìdánilójú.
Ó wà rọ́ Ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin láti fún àwọn Ológun túntún náà ní ìyí tó yẹ́.
Leave a Reply