Ààrẹ Tinubu Kọ̀ Ìwé Sí Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣojú Ṣòfin Lórí Àwọn Olórí Ologún Túntún
Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Bola Ahmed Tinubu tí kọ̀wé sí Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣojú ṣòfìn látí ṣé àkíyèsí àwọn olórí ológun títún ní orílẹ̀-èdè yìí.
Agbẹnusọ ilé-ìgbìmọ̀ aṣojú ṣòfin Honourable Tajudeen Abbas ló ká ìwé náà ní ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin.…