Take a fresh look at your lifestyle.

Osinbajo yóò máa sojú ààrẹ Buhari ní London níbi ìpàdé UN

0 404

igbakeji aarẹ orilẹ ede Naijiria, ọjọgbon Yemi Osinbajo ni yoo maa fi ilu Abuja silẹ lọ si London lati lọ soju  aarẹ  Muhammadu Buhari nibi ipade ijiroro ajọ agbaye lori iyipada ohun amusagbara lorile ede Afirika, paapaa julọ ni orilẹ ede Naijiria.

Agbẹnusọ fun igbakeji aarẹ , Laolu Akande lo tun sọ pe ọjọgbọn  Osinbajo  yoo maa jiroro pẹlu oludari  COP26,  Alok Sharma,ti o jẹ adari ijọba fun orilẹ ede UK  ati alaga fun ijọba ajọagbaye COP26 .

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button