Take a fresh look at your lifestyle.

Nàìjíríà Gbá Owó Mílíọ̀nù Méjì Poun Láti Ró Ètò Ìlera Lágbára

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 328

Ìjọba Nàìjíríà tí gbá àpapọ̀ owó mílíọ̀nù méjì Poun láti ilẹ̀-ọba UK látí fí gbá ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn òṣìṣẹ́ ìlera sí lórílẹ̀-èdè náà.

Aṣojú Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì sí Nàìjíríà, Dókítà Richard Montgomery tó sọ èyí dì mímọ̀ nínú ọrọ̀ kàn, sọ pé òṣìṣẹ́ ìlera tó dangajia pẹ̀lú ìmọ̀ tó péye ṣé pàtàkì fún Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti dènà ikú àìní di àtí láti gbáradì fún èyíkéyìí irọkẹ̀kẹ̀ ààrùn làgbáyé.

Dókítà Montgomery ṣé àlàyé pé UK pèsè owó ìrànwọ́ ìlera náà fún àwọn orílẹ̀-èdè Áfíríkà mẹ́ta bí Kenya, Nigeria, àti Ghana, láti ṣé àtìlẹ́yìn sí àwọn italaya ìlera àgbáyé.

Nibayii, Àjọ Àgbáyé tí Ìlera (World Health Organisation WHO) fí ìdùnnú rẹ̀ hàn bí Orílẹ̀-èdè United Kingdom ṣé ṣé àtìlẹ́yìn ìlera fún awọn òṣìṣẹ́ ìlera tó lágbára fún àwọn ìlera náà àti ìtọjú ìlera àwùjọ ní Nàìjíríà.

Tún kà nípa:Àjọ IoD Gba Àwọn Ọ̀gá Àgbà Ilé-isé Ní Ìmọ̀ràn Láti Máa Gbé Ìgbé Ayé Ìlera Pípé

WHO sọ pé ẹbùn owó náà yóò wúlò fún àkókò ọdún méjì látí ṣé àtìlẹ́yìn fún ìjọba Nàìjíríà láti mú iṣẹ́ ṣíṣe tó dára, àti ipá tí òṣìṣẹ́ ìlera.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button