Nàìjíríà Gbá Owó Mílíọ̀nù Méjì Poun Láti Ró Ètò Ìlera Lágbára
Ìjọba Nàìjíríà tí gbá àpapọ̀ owó mílíọ̀nù méjì Poun láti ilẹ̀-ọba UK látí fí gbá ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn òṣìṣẹ́ ìlera sí lórílẹ̀-èdè náà.
Aṣojú Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì sí Nàìjíríà, Dókítà Richard Montgomery tó sọ èyí dì mímọ̀ nínú ọrọ̀ kàn, sọ pé òṣìṣẹ́…