Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn Onímọ̀ Nípa Àìsàn Suger Sọ Wí Pé Ẹja Funfun Dára Fún Ìlera Ará Wọn.

125

Onímọ̀ nípa àìsàn Suger Dọ́kítà Ayuba Mugana pẹ̀lú ilé ìwòsàn Abubakar Tarawa ni ìpínlẹ̀ Bauchi tí gbà àwọn ènìyàn tó ni àìsàn Suger lamoran láti túnbọ̀ ma eja Funfun fún Àlàáfíà agọ ará wọn.

Ó gbà wọn lamoran yìí nìgbà tí wọn fi ọrọ wá lẹnu wò, ní bè o ti sàlàyé wí pé ní pa jíjẹ ẹja funfun ń ṣe ìrànlọ́wọ́ fún ìwòsàn àìsàn Suger

Ó tèsíwájú wí pé anfààní nlá ló wá nínú jíjẹ ẹja nítorí àwọn èròjà pàtàkì

Ó ni ẹja ni iṣẹ ìtùmọ̀ nínú, ẹ̀jẹ̀, egungun, ẹdọ àti awọ ará

Comments are closed.

button