Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjọba àpapọ̀ ṣe àgbékalẹ̀ ìdá mẹ́wàá nínú ìdá ọgọ́rùn ún Fún ètò ibaraẹniṣepọ àwọn abarapá – Mínísítà

0 147

Ìjọba àpapọ̀ ti ṣe àgbékalẹ̀ ìdá mẹ́wàá nínú ìdá ọgọ́rùn ún awọn eto ibaraẹniṣepọ Fún àwọn abarapá (PwDs).

Dokita Betta Edu, Minisita eto aanu ati igbogunti ipọnju sọ eyi ni Abuja nigba ti o n ṣe ifilọlẹ awọn eto ironilagbara ti igbimọ ti n mojuto ọrọ awọn abarapa ṣe agbatẹru. (NCPWD).

O sọ pe aarẹ Bọla Tinubu ti pa laṣẹ pe ki ijọba fun awọn abarapa ni amojuto to rinlẹ ninu eto agbekalẹ rẹ.

Minisita tun kede agbekalẹ ọgọrun ẹgbẹrun Naira fun ikọọkan ninu awọn to janfaani ẹrọ tin funni lowo fun iranlọwọ lati bẹrẹ okowo.

Alaga, ile igbimọ aṣoju to n risi ọrọ awọn abarapa, Ọgbẹni Bashiru Dauda, fi da awọn ọmọ Naijiria loju pe ẹgbẹ ohun yoo jẹ ki ofin ti yoo daabobo ẹtọ awọn abarapa ni Naijiria fẹsẹ mulẹ.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button