Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Liberia Gbá Àbájáde Èsì Ìdìbò

0 130

Ààrẹ Liberia George Weah tí gbá àbájáde èsì ìdìbò tó wáyé ní ọjọ́ Ẹtì, èyí tí alatako rẹ̀ Joseph Boakai bóri, èyí tó fí òpin sí ẹsùn àríyànjiyàn èsì ìbò tí yóò ṣé ìrànlọ́wọ́ fún ìgbé ìjọba sílẹ̀.

Boakai, 78, Ìgbákejì Ààrẹ tẹ́lẹ̀ rí, tó pàdánù sí ọwọ́ Weah nínú ìdìbò 2017, pẹ̀lú ìwọ̀n ìdá méjì lè díẹ̀ (50.9%) tí ibò Weah’s jẹ́ (49.1%), pẹ̀lú kíkà gbogbo àwọn ibò tí wọ́n di, ìgbìmọ̀ éléto ìdìbò tí orílẹ̀-èdè náà sọ.

Tún ká nípa:Iṣé Élétò Ìdìbò Liberia Tí Ń Ká Àbájáde Ibò Ọjọ́ Ìṣẹgun

Àbájáde èsì náà jẹ́ àmì ìyípadà nlá kán láti ọdún 2017, nígbàtí àgbábọ́ọ̀lù tẹ́lẹ̀ rí náà bóri Boakai pẹ̀lú ìdá méjì-lè-lọgọ́ta.

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ló wá tí ní irẹwẹsi ọkàn pẹ̀lú aini ìlọsíwájú: Òṣì, aini-iṣẹ́, ewú oúnjẹ àti ìpèsè iná mọ̀nàmọ́ná tí kò dára.

Leave A Reply

Your email address will not be published.

button