Take a fresh look at your lifestyle.

Ìdìbò Ti Bẹ̀rẹ̀ Ni Pẹrẹwu Ní Àwọn Ìpínlẹ̀ Gbogbo Lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

0 296

Ìdìbò yíyan Gómìnà àti asojú ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ní àwọn ìpínlẹ̀ gbogbo ti n wáyé báyìí.

 

Ni òwúrọ̀ kutukutu ni agọ mẹ̀jọ kọja isẹju márùn-ùn ni ìdìbò o bẹ̀rẹ̀ ní Duste ni ìjọba ìpínlẹ̀ Jigawa .

 

Àwọn elẹ́tò ìdìbò ti wa ni ìkàlẹ̀ láti agọ mẹ́jẹ aabọ òwúrọ̀ fún ètò ìdìbò náà.

Àwọn òṣìṣẹ́ elẹ́tò ààbò pátápátá lo wa ni ìkàlẹ̀ fún ìrànlọ́wọ́ lórí ètò ìdìbò náà.

 

Ìròyìn fí tó wà létí wí pé ní ìpínlẹ̀ Kwara agọ mẹ́jẹ aabọ òwúrò ni ìdìbò ti bẹ̀rẹ̀.


Ni ìpínlẹ̀ Adamawa ni Yika, agọ méje ni gbogbo ètò ti tó.

Ni ìpínlẹ̀ Benue ati agọ mẹ́fà àárò ni àwọn àjọ elẹ́tò ìdìbò tí dé fún ètò ìdìbò náà.

 

Ìdìbò ti bẹrẹ níbi gbogbo báyìí.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button