Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Tag

#ìdìbò_Gómìnà_Ọdùn_2023

Ibi tí Àjọ INEC yóò ti ṣe àkójọ èsì ìdìbò Gómìná ọdún 2023 Ti Ìpínlẹ̀ Jigawa.

Ibí yìí ni wọn yóò ti máa kó àwọn èsì ìbò ti Gómìnà ìpínlẹ̀ àti èsì ìbò ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ jọ. Ibí yìí bákan náà ni wọn yóò ti máa kéde ẹni tó bá jáwé olúborí nínú ètò ìdìbò Gómìnà ati ilé Ìgbìmọ̀ aṣòfin ti ìpínlẹ̀ Jigawa…

Àbájáde Ìdìbò Gómìná Àti Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́: Makinde jáwé Olubori Ní Ibùdó Ìdìbò…

Gẹgẹ bí àbájáde ìdìbò Gómìnà àti ilé Ìgbìmò Aṣòfin Ìpínlè ṣe bẹrẹ lẹyìn tí ìdìbò parí, Gómìnà Seyi Makinde ti ẹgbẹ́ òṣèlú PDP jáwé olubori ní ibùdó ìdìbò rẹ. Nígbà tí oṣiṣẹ Àjọ Eleto Ìdìbò to mójú tó ètò idibo ati kíka èsì àbájáde rẹ ni…

Ìdìbò 2023: “Ẹgbẹ́ Òṣèlú APC Yóò Tẹ̀síwájú Láti máa Ṣe Dáadáa”-Ààrẹ Buhari

Ààrẹ Muhammadu Buhari ti ṣe afihan rẹ̀ pé àbájáde ìdìbò Gómìnà àti Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ìpínlẹ̀ yóò dáa fún ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress, APC, jákèjádò orílẹ̀-èdè náà. O ni àwọn ọmọ Naijiria mọ ẹgbẹ naa si "ohun ti o sọ, ni…

Àwọn Olùdíje fún ipò Gómìnà lábẹ́ àsìá ẹgbẹ́ Òṣèlú PDP, ACCORD Àti SDP Ti Dìbò Wọn Ní…

Olùdíje fún Ipò Gómìnà lábẹ́ àsìá ẹgbẹ́ òṣèlú PDP, Siminalayi Fubura àti ìyàwó rẹ̀ di ibò wọn ní Ibùdó Keji, Wọ́ọ̀dù Karùn ún, ìlú Opobo, ìjọba ìbílẹ̀ Opobo/Nkoro, ipinle Rivers. Ọ̀gbẹ́ni Fubura nígbà tí ó ń bá àwọn oníròyìn…

Inú Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Dùn sí bí Ètò Ìdìbò ṣe ń lọ ní Ìrọwọ́-Rọsẹ̀ 

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ, Ọ̀gbẹ́ni Seyi Makinde ti fi ìdùnnú rẹ̀ hàn pẹ̀lú àríwòye pé ètò ìdìbò láti yan Gómìnà àti àwọn ọmọ ilé ìgbìmọ̀ asòfin se ń lọ déédé ní ìpínlẹ̀ náà. Ó fi ìdùnnú rẹ̀…

Ìdìbò Gómìná 2023: Bí Ètò Ìdìbò Ṣe Ń Lọ Ní Ìlú Ìbàdàn

Ètò idibo ti bẹrẹ ni ìlú Ìbàdàn tíì ṣe olú ìlú Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Ní ìjọba Ìbílẹ̀ Ìlà Oòrùn Àríwá Ìbàdàn tí Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Seyi Makinde ti ẹgbẹ òṣèlú PDP ti dibo, àwọn oṣiṣẹ Àjọ Eleto Ìdìbò, INEC dé ibùdó ìdìbò náà lásìkò ti ètò àyẹwò…