Ìdìbò o ti bẹ̀rẹ̀ ni agbegbe Obodo àti Abakaliki ni ìpínlẹ̀ Ebonyi látàrí wí pé àwọn ará ìlú kọ lati jade wa dìbò lásìkò.
Àjọ elẹ́tò ìdìbò ti wà ní àwọn agbègbè náà ti wọn sì ti gbáradì fún ìdìbò láti bẹ̀rẹ̀ ní perewu.
Àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú gbogbo lo wa ní ìkàlẹ̀ láti mójú tó ohun tó nlọ.
Awọn oṣiṣẹ aláàbò náà ò gbẹ́yìn láti rí wí pé òhun gbogbo lo ni àlàáfíà lai si wàhálà kankan.