Take a fresh look at your lifestyle.

Ìbò Dídì Bẹ̀rẹ̀ Pẹrẹu Ní Ìlú Kano, Tí Àwọn Ọmọ Ológun Náà Sí Dúró Wámúwámú

0 247

Ìbò dídì ti Gómìnà àti Ilé Aṣòfin ti bẹ̀rẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Kano àti gbogbo àgbègbè rẹ̀ pẹ̀lú àdúrótì àwọn ọmọ ológun.

 

Àjọ INEC náà sì ti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ wọn ní pẹrẹu.

Bí ìbò dídì ṣe ń lọ ní ikọ̀ àwọn ẹ̀sọ́ ń káàkiri pẹ̀lú ọkọ̀ wọn láti pèsè ààbò tó yẹ.

Ibùdó ìbò ti wọ́n ṣe àbẹ̀wò sí ni wọ́n ti rí ikọ̀ ọmọ ogun ókéré tán márùn-ún tàbí jùbẹ́ lọ ikọ̀ àwọn aláàbò tó dúró Wámúwámú.

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button