Ìdìbò Gómìná: Bí Ètò Ìdìbò Gomina àti Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ṣe Ń Lọ ní ìpínlẹ̀ Jigawa
Àyẹ̀wò orúkọ bẹrẹ ni kutukutu òwúrọ̀ ní déédé aago mẹjọ aabọ ki ibo to bẹrẹ ni ile-iwe alakọbẹrẹ ti kasarau ẹka kẹfà ní ìjọba ìbílẹ̀ Dutse, olú-ìlú ìpínlẹ̀ Jigawa.
Nọ́mbà àwọn oludibo ti wọn fọwọsi jẹ: 1,215.
Bákan náà, ni ẹka idibo kẹjọ, àwọn to forukọsilẹ tó ẹẹdẹgbẹrin àti ní ẹka kẹsan ní ile-iwe alakọbẹrẹ ti kasarau, ìjọba ìbílẹ̀ Dutse, olú-ìlú ìpínlẹ̀ Jigawa
Leave a Reply