Take a fresh look at your lifestyle.

ìdánilẹ́kọ̀ọ́ Ìkẹ́kọ̀ Bẹ̀rẹ̀ Fún Àwọn Olùkọ́ní Ní Ìpínlẹ̀ Ebonyi

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 222

Àjọ tó ń pèsè iṣẹ́ ní orílẹ̀-èdè yìí (National Directorate of Employment NDE) ní Ìpínlẹ̀ Ebonyi ní Gúúsù ìlà oòrùn Nàìjíríà tí bẹ̀rẹ̀ ikẹkọ àgbàrá fún àwọn olùkọ́ní rẹ̀.

ìdánilẹ́kọ̀ọ́ náà wáyé látí fí awọn òun èlò ìgbàlódé kọ́ àwọn olùkọ́ni ní Abakaliki Olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Ebonyi.
Nígbà tí o nsọ̀rọ níbí ayẹyẹ ọlọjọ mẹ́ta tí a sami sí pẹ̀lú ”Ikẹkọ tí Àwọn olukọni.”

Tún kà nípa: Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kwara Ràwọ Ẹ̀bẹ̀ Sí Àwọn Aráàlú Látí Dẹkùn Wiwà Kànga Lọ́nà Ìgbàlódé

Olùdarí Gbogbogbò tí NDE, Mallam Abubakar Nuhu, tí Olùdarí Ìpínlẹ̀ náà, Don Anaba ṣójú rẹ̀ sọ pé ìdánilẹ́kọ̀ọ́ náà wá làti ríi dájú pé ìṣòro áìníṣẹ́ dínkù ní orílẹ̀-èdè yìí.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button