Olùdíje fún ẹgbẹ́ òṣèlú APC, Bola Tinubu ti lọ dìbò ní Bourdillion, Ikoyi, ní Ìpínlẹ̀ Èkó
Olùdíje fún ẹgbẹ́ òṣèlú APC, Bola Tinubu àti Iyawo rẹ̀ Remi Tinubu ti lọ dìbò ní Bourdillion, Ikoyi, ní Ìpínlẹ̀ Èkó. Àwọn eniyan rẹ ni ẹgbẹ́ oṣelu APC náà tẹle lọ dìbò

Ó sọ pé, ètò ìdìbò yìí yóò lọ ni ìrọwọ́-rọsẹ̀, ó sì tún sọ pé, ó dá òun lójú wípé, òun yóò jáwé olúborí.
Ọláyinká Akíntọ́lá.
Leave a Reply