Take a fresh look at your lifestyle.

Ọbabìnrin Elizabeth Ń gba Ìtọ́jú Lọ́wọ́

0 310

 

Ìròyìn láti ààfin ọba sọpé, Ọbabìnrin Elizabeth ń gba ìtọ́jú lọ́wọ́ látàrí ìlera rẹ̀ tí àwọn Dókítà sọpé kò péye  tó.

Wọ́n sì ti fi èyi tó àwọn ẹbí rẹ̀ létí.

Ìkéde yìí wá lẹ́yìn tí Ọbabìnrin, ẹni ọdún mẹ́rìn dín lọ́gọ̀rún kúrò níbi gbọ̀ngàn ị̀pàdé orí afẹ́fẹ́ kan ní ọjọ́ ọjọ́rú tí àwon dókítà sì rọ̀ pé kó lọ simi.

Aare Liz Truss sọpé òun àti gbogbo ènìyàn ní orílẹ̀ èdè aláwò funfun ni ìlera rẹ̀ àti ẹbi rẹ̀ jẹ lógún.

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button