Àjọ iṣọkan tó ń mójú tó ètò oúnjẹ àti iṣẹ́ àgbẹ̀ lagbaye (FAO), ti tako bí wọ́n ṣe n pàdánù aginjù látàrí pípa igbó run.
Gẹgẹ bi FAO ti ṣalaye, awọn aginju agbaye wa lọwọ ewu,nitori pe o ti le- nirinwo miliọnu eeka aginju to ti parun lati bii ọgbọn ọdun sẹyin.
Leave a Reply