Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí ń darí ìpàdé Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ àpapọ̀ lórí ayélujára ní gbọ̀ngàn ìgbìmọ̀, ní ọ́fíísì Ààrẹ, Víllà ní ìlú Àbújá.


Awọn ti o wa nibi ipade naa ni Akọwe agba fun Ijọba apapọ, Boss Mustapha ati Olori awọn oṣiṣẹ ijọba apapọ, Dokita Fọlaṣade Yẹmi-Ẹsan.
Awọn minisita to wa nibẹ ni ; Minisita fun ibaraẹnisọrọ ati Asa, Lai Mohammed, Isuna, Zainab Ahmed, Aviation, Hadi Sirika, ati ti iṣẹ, Dokita Chris Ngige.


Awọn miiran to tun wa nibẹ ni: Minisita fun Agbara, Abubakar Aliyu, Imọ Sayẹnsi ati amayedẹrun, Mamora Olorunnimbe, ọrọ Niger Delta , Umana Umana ati Awọn orisun omi, Suleiman Adamu.

Awọn minisita toku n kopa lati awọn ọfiisi wọn ni Abuja lori ayelujara.
Ipade naa waye latarii fífi ìwé iṣẹ́ àkànṣe ojú ọjọ́ lọ́lẹ̀ nipasẹ iṣakoso to n lọ lọwọlọwọ bayii lati 2015 di 2022.
Alaye kikun nigbamii……..
[…] Tún kà nípa:Ààrẹ Bùhárí ń darí àpèjọ ìgbìmọ̀ aláṣẹ àpapọ̀ […]