Orílẹ̀-èdè Philippine bẹ̀rẹ̀ ìdìbò láti yan Ààrẹ tutun ní ọjọ́ ajé àti ẹgbàásán
òṣìṣẹ́ mìíràn láti gbogbo àwọn ìpele ìjọba.
Awọn oludije ti wọn yoo yan ni igbakeji aarẹ,awọn aṣofin mejila, awọn ọmọ ẹgbẹ Ile-igbimọ Aṣoju ti o ju ọọdunrun lọ ati awọn oṣiṣẹ ijọba agbegbe ti o ju ẹgbàájọ lọ.
Ijọba ti fi awọn ọmọ ogun ẹ̀ẹ́dẹ́gbàta ĺe ńi ọ̀kẹ́ mèjì ati awọn osiṣẹ
ọlọpa ọ̀kẹ́ mẹ̀ta ṣe alabojuto eto alaafia lakoko awọn idibo.
Afikun ọlọpa ẹgbàáfà wa ni imurasilẹ ti iwa-ipa nle ba waye ni awọn agbegbe kan.
Leave a Reply