Akọ̀wé Gbogbogboò fún àjọ àgbáyé UN, Ọ̀gbẹ́ni Antonio Guterres ti tẹnumọ ìpinnnu àjọ náà láti ríi dájú pé ìrànlọ́wọ́ àwọn olùfaragbà Boko Haram àti Ènìyàn tí wọ́n fipá ṣí nípò ní Àríwá-Ilà-oòrùn Nàìjíríà jẹ wọ́n lógún.
Akọwe agba fun ajọ agbaye, Antonio Guterres lo sọ eyi nigba to gunle si Maiduguri, olu ilu ipinlẹ Borno, Ariwa ila oorun Naijiria.
Ọgbẹni Guterres ki Gomina Ipinlẹ Borno fun ise ribiribi to n ṣe.
O tun ṣe akiyesi pe ṣiṣe iwadi ipilẹ ipanilaya – ati eto imulo ijọba, eyiti yoo mu igbẹkẹle kikun wa laarin awọn eniyan ati ijọba jẹ ẹya pataki ti o han gbangba.
Leave a Reply