Take a fresh look at your lifestyle.

Ayẹyẹ ọdún Àsun ní ìpínlẹ̀ Òǹdó

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 435

Ọdún Àsun èyí tí ó bẹ̀r̀ẹ ní ọdún tó kọjá ní ìpínlẹ̀ Òǹdó ti ṣetán láti ṣe ẹlẹ́ẹ̀kejì rẹ̀ ní ọjọ́ kejì, Oṣù Karùn ún,ọdún 2022.

Destination Ondo labẹ aarẹ La Campgne,Ọtunba Wale Akinboboye,lo da Ayẹyẹ naa,eyi ti o bẹrẹ lodun to koja silẹ,ti ijoba ipinlẹ Ondo si fọwọsi lẹyin naa.

Ayẹyẹ naa ti yoo ṣagbatẹru ni ifọwọsowọpọ pẹlu ile iṣẹ ijọba fun asa ati irin-ajo nipinlẹ Ondo, yoo waye ni papa isere ilu Ondo.

Awọn alejo, agbegbe ibilẹ ati awọn olukopa miiran ni wọn yoo fi ọpọlọpọ  ere idaraya ati eto lọlọkanọjọkan dalaraya lẹyin ti awọn alariya, awọn ẹgbẹ oriṣiriṣi ati awọn ikọ ayẹyẹ naa yoo tọpa opopona.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button