Ìpínlẹ̀ Cross River Yóò Fún Ọ̀kẹ́ Màrún-din-ni-àádọ́ta (900,000) Ọmọdé Ní Abẹ́rẹ́ Àjẹsára Còrónà
Ilé-iṣẹ́ ìdàgbàsókè ìlera alákọ̀bẹ́rẹ̀ ti Cross River ti bẹ̀rẹ̀ àjẹsára ti àwọn ọmọdé tí kò tìí dàgbà ju ọgọ́ta oṣún lọ
Adari agba fun ajọ naa, Dokita Janet Ekpenyong lo sọ eyi lasiko ayẹyẹ kan lati ṣe afihan eto ajesara ropa-rose ni ilu Calabar, olu ilu ipinlẹ Cross River, ni guusu Naijiria.
Leave a Reply