Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrùn Còrónà Ti Bẹ́ Sílẹ̀ Nínú Ikọ̀ Tottenham

0 180

Ìgbáradì  ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù Tottenham fún àwọn ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ tí wọ́n ní ní àsìkò Kérésìmesì ti forí sópón nítorí ìbẹ́sílè ààrùn coronavirus nínú ikọ̀ náà.

Ọpọlọpọ agbabọọlu pẹlu osisẹ wọn ni esi ayẹwo wọn ti fihan pe wọn ti ni aarun Corona ti eyi si ti ṣe idiwo fun awọn igbaradi wọn fun awọn idije ti wọn ni.

Leave A Reply

Your email address will not be published.