Ẹgbẹ́ ADP ti gba ààrẹ Buhari níyànjú láti kọ orúkọ rẹ̀ ní góòlù sínú ìwé ìtàn Nàìjíríà nípa fífọwọ́ sí àtúnṣe òfin ìdìbò
Alaga ẹgbẹ ADP, Ọgbẹni Yabagi Sani, sọ pe yoo jẹ oun ibanujẹ fun ijọba ati Aarẹ fun ra rẹ, ti o ba tẹriba fun imọran awọn ọmọ ẹgbẹ rẹ lati mase towo bo atunse na
Leave a Reply