Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹgbẹ́ ADP Rọ Ààrẹ Buhari Láti Fi Ọwọ́ Sí Àtúnsẹ Òfin Ìdìbò

0 148

Ẹgbẹ́ ADP ti gba ààrẹ Buhari níyànjú láti kọ orúkọ rẹ̀ ní góòlù sínú ìwé ìtàn Nàìjíríà nípa fífọwọ́ sí àtúnṣe òfin ìdìbò

Alaga ẹgbẹ ADP, Ọgbẹni Yabagi Sani, sọ pe yoo jẹ oun ibanujẹ  fun ijọba ati Aarẹ fun ra rẹ, ti o ba tẹriba fun imọran awọn ọmọ ẹgbẹ rẹ lati mase towo bo atunse na

Leave A Reply

Your email address will not be published.