Take a fresh look at your lifestyle.
Democracy

A ń Sisẹ́ Pẹ̀lú Ìlànà Ẹrọ Dígítà Títí Ọdún 2025

0 141

Aláṣẹ àwọn ibùdó ọkọ̀ ojú omi Nàìjíríà (NPA) ti ṣàlàyé ṕe ètò ti wà ní pẹsẹ́ láti ri wí pé ẹ̀ka ibùdó ọkọ̀ ọjú omi Nàìjíríà sisẹ́ pẹ̀lú ìlànà imọ ẹrọ ayelujara, iyẹn dígítà tí yóò bá fi da ọdún 2025

Oludari Alakoso ti NPA, Ọgbẹni Mohammed Bello-Koko, lo sọ eyi lati inu atẹjade kan, ni ọjọ abameta ni ilu Eko.

Leave A Reply

Your email address will not be published.