Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí gúnlẹ̀ sí ìlú Àbújá lẹ́yìn EXPO 2021

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 374

Ààre Mùhámmádù Bùhárí ti gúnlẹ̀ sí Àbújá lẹ́yìn tí ó kópa nínú EXPO 2020 ní Dubai, United Arab Emirates.

Aarẹ gunlẹ  si abala papakọ ofurufu Nnamdi Azikiwe nilu Abuja ni nnkan bi aago meji abọ kọja iṣẹju meji  (2:32 GMT).

Ọga agba fun Awọn oṣiṣẹ rẹ, ọjọgbon Ibrahim Gambari ati Minisita fun olu-ilu , Mohammed Bello ati awọn olori awọn ile-iṣẹ aabo ni wọn gba wọle bo ṣe n gunlẹ.

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button