Igbákejì ààrẹ Òsínbàjò yóò fọ̀rọ̀jomitoro ọ̀rọ̀ níbi àpèjọ ìgbìmọ̀ àgbáyé ilé iṣẹ́ tó ń mójútó afẹ́fẹ́ gáásì ti ọdún 2021 LPG
Eyitayọ Fauziat Oyetunji
Igbákejì Ààrẹ Nàìjíríà, ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmi Ọ̀sínbàjò ní ọjọ́bọ̀ yóò fọ̀rọ̀ jomitoro ọrọ níbi àpèjọ àgbáyé ilé-iṣẹ́ tó ń mójútó afẹ́fẹ́ gáásì ní Dubai, United Arab Emirates.
Oluranlowo pataki fun aarẹ lori ọrọ iroyin ati Ipolongo, Ọfiisi ti Igbakeji Aare, Laolu Akande sọ ninu atẹjade kan pe, Osinbajo yoo kuro Abuja ni kutukutu owurọ ọjọ aje lati kopa ninu apejọ naa.
Akori apejọ naa , eyiti o awọn aṣoju to to ẹgbẹrun meji lati orilẹ-ede mejile-laadọrin yoo kopa ninu rẹ ni “Ọsẹ LPG: “Agbara Ọla.”
Leave a Reply