Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti kìlọ̀ fún àwọn olùdarí káàkiri àgbáyé nípa ewu ti o rọ mọ aikari ògùn COVID-19 láàrín àwọn orílẹ̀-èdè tó sès̀e ń dàgbà sókè ti èyí sì le jẹ́ ìpalára fún ìlọsíwájú tí ó wà nílẹ̀
Ilu Madrid, orilẹ ede Spain ni Minisita fun Aṣa, Lai Mohamme ti ṣe ikilọ naa, ni ọjọ Ọjọbọ nibi Apejọ ẹlẹkerinlelogun gbogboogbo Ajo Aririnajo Agbaye (UNWTO).
Ninu alaye lati ẹnu Minisita naa, o ṣalaye pe anfaani lati lo awọn ogun yi yẹ ki o da lori ẹtọ ti gbogbo eniyan gbodo gbadun nipa eto ilera lai si iyasoto ẹya, ẹsin, igbagbọ oloselu tabi eto-ọrọ aje.
Tolulope Akinseye
Leave a Reply