Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Buhari Balẹ̀ Sí Ìlú Dubai

0 278

Ààrẹ Muhammadu Buhari ti balẹ̀ sí Dubai, United Arab Emirates láti kópa nínú àpérò EXPO 2020.

Ààrẹ dé ìlú Dubai ní òwúrọ̀ ọjọ́ Ojóbò; asojú Nàìjíríà sí UAE, Mohammed Rimi àti Ambassador UAE sí Nigeria, Dr Fahad Al-Taffaq wà ní pẹsẹ́ láti kíi káàbọ̀

Apero naa yoo jẹ anfaani fun awọn aṣoju Naijiria lati ṣe afihan awọn ilọsiwaju pataki ninu eto-ọrọ aje ti wọn ti sẹ fun ọdun mẹfa sẹyin gẹgẹ bi ipilẹ funlati jẹ ki orilẹ-ede wa loke agba ninu  idoko-owo okeere.

Tolulope Akinseye

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button